Itan Yoruba

  • 6.0 MB

    Tamaño de archivo

  • Android 4.0.3+

    Android OS

Acerca del Itan Yoruba

Itan Yoruba fún gbogbo ọm Yoruba nílẹ̀ àti lẹ́hìn odi

1. Itan Yoruba fún gbogbo ọmọ Yoruba nílẹ̀ àti lẹ́hìn odi.

2. Laji Abbas jẹ́ ọ̀kan pàtàkì lára àwọn oluwadi ìjìnlẹ̀ nípa ìtàn Yorùbá àti ohun gbogbo tó bá jẹ mọ́ àṣà Yorùbá.

Ìlànà tó yanjú la fi ńṣe iwadi pẹ̀lú yíyọ àlọ́ àti àròsọ kúrò lára ìtàn nítorí àlọ́ ṣe ọ̀pọ̀ àkóbá fún Itan wa, pẹlu bo se jẹ́ pé apọnpa pọ̀ nínú ìtàn wá Laji Abbas tún gbìyànjú pupọ lórí bí ó ṣe ń yọ àwọn apọnpa bẹ kúrò lára ìtàn pẹ̀lú a ti mọ tọ́ka sí àwọn ìwé Itan tó ti wà tipẹ àti àwọn tí Laji Abbas gan lọ gba ìtàn lẹ́nu wọn.

Ìdí nìyí tí ọ̀pọ̀ èèyàn fi npe Laji Abbas ni Olùkọ́ Àgbà nínú àwọn tó nsọ ìtàn loni.

Ìtàn Yorùbá wá fún gbogbo ọmọ Yoruba àwa náà sí le kopa tí wá nípa bí ogún ńlá yí a ṣe jẹ́ ìtẹ́wọ́gbà kárí ayé.

Mostrar másMostrar menos

Novedades más recientes 9.2

Last updated on 2019-08-20
Itan Yoruba fún gbogbo ọmọ Yoruba nílẹ̀ àti lẹ́hìn odi

Versiones Antiguas de Itan Yoruba

Descarga rápida y segura a través de APKPure App

¡Un clic para instalar archivos XAPK/APK en Android!

Descargar APKPure