Itan Yoruba

Itan Yoruba

web minister apps
2019年08月20日
  • 6.0 MB

    文件大小

  • Android 4.0.3+

    Android OS

關於Itan Yoruba

Itan Yoruba fún gbogbo ọmọ Yoruba nílẹ̀ àti lẹ́hìn odi

1. Itan Yoruba fún gbogbo ọmọ Yoruba nílẹ̀ àti lẹ́hìn odi.

2. Laji Abbas jẹ́ ọ̀kan pàtàkì lára àwọn oluwadi ìjìnlẹ̀ nípa ìtàn Yorùbá àti ohun gbogbo tó bá jẹ mọ́ àṣà Yorùbá.

Ìlànà tó yanjú la fi ńṣe iwadi pẹ̀lú yíyọ àlọ́ àti àròsọ kúrò lára ìtàn nítorí àlọ́ ṣe ọ̀pọ̀ àkóbá fún Itan wa, pẹlu bo se jẹ́ pé apọnpa pọ̀ nínú ìtàn wá Laji Abbas tún gbìyànjú pupọ lórí bí ó ṣe ń yọ àwọn apọnpa bẹ kúrò lára ìtàn pẹ̀lú a ti mọ tọ́ka sí àwọn ìwé Itan tó ti wà tipẹ àti àwọn tí Laji Abbas gan lọ gba ìtàn lẹ́nu wọn.

Ìdí nìyí tí ọ̀pọ̀ èèyàn fi npe Laji Abbas ni Olùkọ́ Àgbà nínú àwọn tó nsọ ìtàn loni.

Ìtàn Yorùbá wá fún gbogbo ọmọ Yoruba àwa náà sí le kopa tí wá nípa bí ogún ńlá yí a ṣe jẹ́ ìtẹ́wọ́gbà kárí ayé.

更多

最新版本9.2的更新日誌

Last updated on 2019年08月20日
Itan Yoruba fún gbogbo ọmọ Yoruba nílẹ̀ àti lẹ́hìn odi
更多

視頻和屏幕截圖

  • Itan Yoruba 海報
  • Itan Yoruba 截圖 1
  • Itan Yoruba 截圖 2
  • Itan Yoruba 截圖 3
  • Itan Yoruba 截圖 4
  • Itan Yoruba 截圖 5
  • Itan Yoruba 截圖 6
  • Itan Yoruba 截圖 7

Itan Yoruba歷史版本

Itan Yoruba 9.2

6.0 MB2019年08月20日
下載
APKPure 圖標

在APKPure極速安全下載應用程式

一鍵安裝安卓XAPK/APK文件!

下載 APKPure
thank icon
We use cookies and other technologies on this website to enhance your user experience.
By clicking any link on this page you are giving your consent to our Privacy Policy and Cookies Policy.
Learn More about Policies