Itan Yoruba

Itan Yoruba

web minister apps
Aug 20, 2019
  • 6.0 MB

    파일 크기

  • Android 4.0.3+

    Android OS

Itan Yoruba 정보

Itan Yoruba fún gbogbo ọmọ 요 루바 어

1. Itan Yoruba fún gbogbo ọmọ Yoruba nílẹ̀ àti lẹ́hìn odi.

2. Laji Abbas jẹ́ ọ̀kan pàtàkì lára àwọn oluwadi ìjìnlẹ̀ nípa ìtàn Yorùbá àti ohun gbogbo tó bá jẹ mọ́ àṣà Yorùbá.

Ìlànà tó yanjú la fi ńṣe iwadi pẹ̀lú yíyọ àlọ́ àti àròsọ kúrò lára ìtàn nítorí àlọ́ ṣe ọ̀pọ̀ àkóbá fún Itan wa, pẹlu bo se jẹ́ pé apọnpa pọ̀ nínú ìtàn wá Laji Abbas tún gbìyànjú pupọ lórí bí ó ṣe ń yọ àwọn apọnpa bẹ kúrò lára ìtàn pẹ̀lú a ti mọ tọ́ka sí àwọn ìwé Itan tó ti wà tipẹ àti àwọn tí Laji Abbas gan lọ gba ìtàn lẹ́nu wọn.

Ìdí nìyí tí ọ̀pọ̀ èèyàn fi npe Laji Abbas ni Olùkọ́ Àgbà nínú àwọn tó nsọ ìtàn loni.

Ìtàn Yorùbá wá fún gbogbo ọmọ Yoruba àwa náà sí le kopa tí wá nípa bí ogún ńlá yí a ṣe jẹ́ ìtẹ́wọ́gbà kárí ayé.

더 보기

What's new in the latest 9.2

Last updated on 2019-08-20
Itan Yoruba fún gbogbo ọmọ Yoruba nílẹ̀ àti lẹ́hìn odi
더 보기

비디오 및 스크린 샷

  • Itan Yoruba 포스터
  • Itan Yoruba 스크린샷 1
  • Itan Yoruba 스크린샷 2
  • Itan Yoruba 스크린샷 3
  • Itan Yoruba 스크린샷 4
  • Itan Yoruba 스크린샷 5
  • Itan Yoruba 스크린샷 6
  • Itan Yoruba 스크린샷 7

Itan Yoruba의 오래된 버전

Itan Yoruba 9.2

6.0 MBAug 20, 2019
다운로드
APKPure 아이콘

APKPure 앱을통한매우빠르고안전한다운로드

한번의클릭으로 Android에 XAPK/APK 파일을설치할수있습니다!

다운로드 APKPure
thank icon
사용자 환경을 개선하기 위해 이 웹 사이트의 쿠키 및 기타 기술을 사용합니다.
이 페이지의 링크를 클릭하면 당사의 개인 정보 보호 정책쿠키 정책에 동의하는 것입니다.
더 알아보기